@Judaixxspexxy@okx Kim boys got nothing on them those folks operate more or less like traditional banks ; sophisticated tech
To be sincere i trust @okx and @wallet
Kí ni GenLayer?
GenLayer kìí ṣe fún ìlú kan tàbí orílẹ̀-èdè kan ṣoṣo ti gbogbo ayé ni! Ó jẹ́ ìmọ̀-ẹrọ ìgbàlóde tó gbámúṣé tó ń so ọgbọ́n atọwọ́dá (AI) àti ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ (blockchain) pọ̀ láti jẹ́ kí ọjọ́ iwájú rọrùn, kí ó sì wà ní ìmúṣé fún gbogbo wa.