ASẸTA ALASIRI GIDI TO GBONA
Ori Akọ Alangba ọjọọ 21
Ẹdan Takọ Tabo Kọọkan
Odidi atare kan { atare tiko mi rara}
Osun
Ikoko tuntun kekere kan
Ẹ lọ Osun yi kunna daadaa
Ẹ fi osun yi ku awọn ori yi
Daaadaaa
Ẹ ko ẹdan tẹlẹ ikoko ijogun
Ẹ to awọn ori yi si lori ẹ gbe
Atare le ẹ jo wọn papọ
Ẹ ma jẹ ki ọmọde sọwa nigba
Ti a ba njo isẹ yi ooo
Ejo papọ ẹ lọ kuna daaadaaa
Ẹni kan to ni ajo yi yio fi niwọn
Ninu ẹtu yi sin gbere 21 sori
Ẹ fi ẹtu yi po ọsẹ dudu daadaa
Ẹ ko awọn ẹdan yẹn tẹlẹ inu
Iko yẹn pada ẹ ko ọsẹ yi le
Lori ẹ lọ gbe ọsẹ yi pamọ dadaa
Ọsẹ inu koko yi ifọri lasan nio
Fun ẹni kan to singbẹrẹ yi nio
Sẹ ri ọsẹ yi lagbara gan
Logijẹ pe ni asiko ti owo
Bawa lọwọ wa, ti ko fibẹ si
Bukata ta fẹ gbọ lo dara ju
Ka lo ọsẹ yi Lera wọn daadaa
O yẹ koti ye wa bayẹn.
ARỌBI ASẸTA MADARIKAN
ẸRỌ NI ISẸ YI LOFI DARA
KI ASETO IRU AWỌN ISẸ YI
FUN AWỌN ỌMỌ WA LATI
KEKERE KI WỌN LO DAADAA
KO WỌRA DAADAA KI WỌN
TO MA NI BUKATA.
Ti aleye yi ko ba ye wa daadaa
To ẹ wo WhatsApp channel mi
Fun ẹkun rẹrẹ alaye yi.
https://t.co/7sJ5iyGSpL
KOJU BAYẸN LỌ IRE O ✌🏽🤍
#alburujy
#asiriogunibile
#ifa
#isese
#YorubaSpirituality