ASIRI PERFUME IBUKUN TODAJU 💯✅
lleke itun 16
lleke ifa 16
Abeere 16
Sawerepepe gbigbe die
Ewe ola die.
A o lo gbogbo re papo, a o daa si inu perfume to ba wu wa, a o maa fi sara jade.
You all are trying to spoil my name, but you failed
Hypocrisy and manipulations everywhere
ATUDE AIYE TODAJU {TESTED AND CONFIRMED}
A o wa odidi okete ooye kan, a o gun pelu ata ijosi die ati eepo obo die ati eepo igi nla pelu ewe orijin die; a o gun papo mo ose dudu.
A o fi ose yii we ninu ajadi apere fun ojo meje leralera pelu omi to lo woorowo.
O daju pa !!!
Bi ahun ba mi akan igba
Ti arigiségi ba ségi
Ori ara e lo fi n ru
This is ARIGISEGI, known as bagworm moth. Too obvious from its name; A worm that breaks tiny trees to make its own housing, camouflage and protection.
Have you seen this before ⁉️⁉️
Tell us in the CS what it is called in your language 🤭🤭
Local Eggs 3
Lime water
Original Honey
Break one egg (each day)
Add little lime water
And original honey
Mix thoroughly and drink for 3 days.
NB: This is only for mild situations, so SFA test to confirm what actually caused the LSC.
Good luck
OSOLE OWO TO N SONI DI OLOWO TOMOTOMO 💯
Odidi abo elede ibile nla kan
Ori oka to lase lenu 3
Ori ere to lase lenu meta
Ori okete to pe daada meta
Ori ikun to pe daada 3
Ori akala to pe daada 3
Ori igun to pe daada meta
A o koko pa odidi elede ooye yi sinu ape to ba tobi
1/3
If you have thousands, you would want to become a millionaire; a millionaire would also want to become a billionaire too and so on….it depends sha 🤷♂️
@Aditu_amoye With all. These you mentioned I am sure we are talking about millions here!!! Anyone that has this kind of money and still want to do this is a thief...
Eye kó awon eyan loku kokoro mo
ALUWO TODAJU TO CONFIRM 💯
A o lo wa oromodie ti iye re ko tii kanle kan, a o la aya re, a o ko oruka si pelu eyo atare mesan; a o lo rii mo oju ona fun odidi ojo meje; to ba di ojo keje, a o lo mu, a o maa ki bo owo fi ja.
ERO RE
Obinrin ni yi o to si lenu !
AKOYA MALU GIDI TODAJU
Ti awon omo alaigboran ba yaju si wa, ise yi ni a fi n ko won logbon.
A o wa edo okete tutu, a o po mo ose daada, a o maa fi ose yi we oju ibi ti won ti na wa.
ERO RE
A o ju ose yi die sinu oti ogogoro fun eni naa ki o mu.
Iwo naa rora se o 🫵🫵🫵
OSOLE TODAJU TO GBONA
Ori ofafa to nirun meji
Ewe ogo tutu
Ewe sawerepepe tutu
A o gun awon ewe yi po mo ori ofafa kan, a o po mo ose, ori ofafa ikeji la o fi tele igba; a o ko ose naa le mole, a o bere wiwe re leyin ojo keje.
OSOLE TODAJU TO GBONA
Ori ofafa to nirun meji
Ewe ogo tutu
Ewe sawerepepe tutu
A o gun awon ewe yi po mo ori ofafa kan, a o po mo ose, ori ofafa ikeji la o fi tele igba; a o ko ose naa le mole, a o bere wiwe re leyin ojo keje.