30 on the 30th!
“Even to your old age and gray hairs I am he, I am he who will sustain you. I have made you and I will carry you; I will sustain you and I will rescue you.”
This is 30! 🥹🎉
30 on the 30th!
“Even to your old age and gray hairs I am he, I am he who will sustain you. I have made you and I will carry you; I will sustain you and I will rescue you.”
This is 30! 🥹🎉
Àṣàkẹ́ ọmọ Ọlọ́jà,
Àkànní ọmọ ẹlẹ́yẹ mọ́lẹ̀.
Ọmọ a tẹ́jú mọ́ni bí ẹni fẹ́ni,
Ọmọ a fọwọ́ tútù mú ni bí ẹni fẹ́ni níyàn.
Àṣàkẹ́, ọmọ onílé ọlà.
Aríwàṣọ̀ bí ẹni mọ̀ọ́ rán,
Obìnrin rere tí ń tọ́jọ́ ọmọ rẹ̀.
Olólùfẹ́ ọmọ, ẹni tí wọ́n ń bá tìtì nà,
Ẹni àwọn ènìyàn ń gbà láti fi omi àánú wẹ̀.
Happy Birthday Asake ❤️🙏
You're beautiful and you know it. 😁