It's a wild wicked world. Squeeze out any happiness you can from it. Celebrate any little wins and dwell on them. Merry on the happy days and bask in them. The sad days would come and there's nothing you can do to keep them away.
Eat with your brothers, don’t compete with them. There’s enough room at the table for everybody who’s willing to grind. The war is against poverty, not the ones you came up with. Never let money turn brothers into enemies. Stay solid, stay locked in, and always have your brother’s back. We hustle together, we eat together, and we rise together. The mission is bigger than any one man, get money, beat poverty, protect the brotherhood.
Mo dúpẹ́ fún ẹ̀mí tí mo rí lò d'èní
Mo dúpẹ́ fún èémí tí mò ń rí mí
Mo dúpẹ́ fún ìwàláàyè mi
Mo dúpẹ́ fún ìwòsàn ọkàn mi
Mo dúpẹ́ fún ìmúláradá orísun mi
Mo dúpẹ́ fún ẹ̀bùn mi
Àti fún ògo t'áa fi dé ẹ̀bùn náà l'ádé
Mo dúpẹ́ fún ìgbàfún àti ìpèsè
Mo dúpẹ́ fún ohun gbogbo
Èyí tí mo là kọjá
Fún ẹwà tí gbogbo experiences yẹn dà kún mi...
Mo dúpẹ́!
Mo join gbogbo Ìṣẹ̀dá
Bí mo ti máa ń ṣe nígbà gbogbo,
Láti f'ògo fún OLÓDÙMARÈ
Ìpìlẹ̀ àti Orísun ohun gbogbo
Bí màá ṣe máa ṣe rèé o
L'áàye e tèmi nínú Ìṣẹ̀dá
In my own space...
Màá kàn ṣáà máa tàn ìmọ́lẹ̀ ONÍÌMỌ́LẸ̀ ni!
Màá kàn máa rí ìmísí láti ọ̀dọ̀ ONÍÌMÍSÍ ni!
Màá kàn máa rí ìránwọ́ tí mo need all the time l'áìníítán ni!
Níwọ̀n ìgbà tí mo bá dúró l'áàyè mi...
Oore ọ̀fẹ́ ni mo fẹ́ síi
Láti dúó d'alẹ́ nínú ìmọ́lẹ̀
Kí àánú l'áìníítán máa accompany mi lọ
Kí n rí ìbùkún u tèmi nínú àsùnwọ̀n ọrọ̀ Ìṣẹ̀dá yí
Kí n ṣ'àṣeyọrí l'ọ́nà a tèmi!
Mo dúpẹ́ pé mo m'ọ̀nà mi!
Ìmọ́lẹ̀ ọ̀tun tàn!
Agbára l'ọ̀tun wá!
Ìbùkún ní bùsọ̀bùsọ̀!
Ẹwà tàn síi!
Happy Birthday to me
Ọm'ỌBA Olúṣọlá Àṣàkẹ́ Arẹ́sẹ̀tẹlẹ̀
IgiOlúgbìn
Ọlátiwà Ọláwàńlẹ̀
Ìríọlá Ìṣeọlá
ẸWÀTÀN!
My kindddd!
Stay!
In your own space!
It pays!
May eyes keep opening.
#yóòdáa! ❤️
The older you get, the more attractive a boring life becomes. Good sleep, enough money, peace of mind and nobody disturbing you starts looking like paradise.
Can you build without applause?
Can you work without feedback?
Can you persist without confirmation?
Can you remain disciplined when nobody is watching?
That season will teach you things applause never could.
Time goes by so fast.
You need to not be afraid of anything.
Live your life without regrets.
See set backs as side quests.
We all have to die someday.
Knowing this is comforting and terrifying at the same time.
But no matter when, everything must end for everyone one day.