@Tunde_Sosina “Ẹ sì máa rìn ní ìfẹ́, gẹ́gẹ́ bí Kristi pẹ̀lú ti fẹ́ wa, tí ó sì fi ara rẹ̀ fún wa ní ọrẹ àti ẹbọ fún Ọlọ́run fún òórùn dídùn." Efesu 5:2
@Tunde_Sosina “And walk in the way of love, just as Christ loved us and gave himself up for us as a fragrant offering and sacrifice to God.”
Ephesians 5:2
MO fara mi fun O
Mo ku nitori re
Ki nle ra o pada
K’o le jinde nn'oku
Mo f 'ara mi fun o
Kini ‘wo se fun Mi?
2. Mo f’ojo aiye Mi
Se wahala fun o
Ki iwo ba le mo
Adun aiyeraiye
Mo lo p'odun fun o
O lo kan fun Mi bi?
🎹🎷🎼🥁🎤🎧🎷🎸
@Tunde_Sosina Matiu 9: 37-38
“Ó bá sọ fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ pé, “Àwọn ohun tí ó tó kórè pọ̀, ninu oko, ṣugbọn àwọn òṣìṣẹ́ kò pọ̀. Nítorí náà ẹ bẹ Oluwa ìkórè kí ó rán àwọn òṣìṣẹ́ sí ibi ìkórè rẹ̀.”
@Tunde_Sosina Matt 9: 37 - 38
“Then he said to his disciples, “The harvest is plentiful but the workers are few. Ask the Lord of the harvest, therefore, to send out workers into his harvest field.”
WA, ma sise
Tani gbodo sole ninu oko
Gbati gbogbo enia nkore jo
'Kaluku ni Baba pase fun pe
“Sise Ioni"
2. Wa, ma sise
Gba' pe giga ti angeli ko ni
Mu hinrere to t‘agba t’ewe lo
Ra gba pada, wawa l’a akoko
nlo Ile su tan
🎹🎼🥁🎤🎧🎷🎸
@DAMIADENUGA Every motivational word is contextual and time-sensitive. What applies in one season may not necessarily apply in another.
Discernment is what helps you know what to embrace, when to apply it, and how to apply it.
@Tunde_Sosina@yomioludemi1 Galatia 2:20: "A ti kàn mí mọ́ àgbélébùú pẹ̀lú Kristi, èmí kò sì wà láààyè mọ́, ṣùgbọ́n Kristi ń gbé inú mi; wíwà tí mo sì wà láààyè nínú ara, mo wà láààyè nínú ìgbàgbọ́ Ọmọ Ọlọ́run, ẹni tí o fẹ́ mi, tí ó sì fi òun tìkára rẹ̀ fún mi."
@Tunde_Sosina@yomioludemi1 I have been crucified with Christ and I no longer live, but Christ lives in me. The life I now live in the body, I live by faith in the Son of God, who loved me and gave himself for me. Gal 2 : 20
GBA aiye mi, Oluwa
Mo ya si mimo fun O
Gba gbogbo akoko mi
Ki nwon kun fun iyin Re
2. Gba owo mi k’o si je
Ki nma lo fun ife Re
Gba ese mi, k’o si je
Ki nwon ma sare fun O
3. Gba ohun mi, je ki nma
Korin f’Oba mi titi
Gba ete mi, jeki nwon
Ma jise fun O titi
🎹🎷🎸🎧🎤🎼🥁🎺🪘
Addendum to Greatness
Messi actually won three major world competitions:
🏆 FIFA World Youth Championship (U20) – 2005
🏆 Olympic Gold Medal (U23) – 2008
🏆 FIFA World Cup – 2022
And in all three tournaments, Messi wasn't just a participant—he was named the tournament's **best player**.
Now, to the other GOAT contender:
Cristiano Ronaldo's only appearance in a comparable age-grade world tournament came at the **2004 Athens Olympics**, where Portugal's campaign was short-lived. The team finished bottom of its group and failed to reach the knockout stage.
Despite being one of Portugal's brightest young stars at the time, Ronaldo was unable to help his team advance.
The contrast is simple: one player left world tournaments with trophies and MVP awards; the other left early.
Football fans can debate many things, but achievements on the world stage are part of the record books forever. 😉🐐🏆
No be today Siuuu dey flop for world stage. *That flopping for international world stage competition na follow come for Siuuuu*