Ẹ wo bí Gómìnà Adémọ́lá Adélékè ṣe dọ̀bálẹ̀ tán fún ẹ̀gbọ́n wọn, Dókítà Dèjì Adélékè láti dúpẹ́ nítorí àtìlẹ́yìn ẹ̀gbọ́n wọn lẹ́yìn ìgbàtí Gómìnà borí nínu ìdìbòyàn Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ti Àbámẹ́ta tó kọjá
#EdeYorubadunlenu#yoruba#osunstate#yorubaculture