FUN anu to po b'iyanrin
Ti mo ngba l’ojumo
Lat' odo Jesu Oluwa
Kini emi o fi fun?
2. Kini ngo fi fun Oluwa
Lat‘ inu okan mi
Ese ti ba gbogbo re je
Ko tile ja mo nkan
3. Eyi l'ohun t'emi o se
F'ohun to se fun mi
Em' o mu ago igbala
Ngo kepe Olorun
🎹🎧🎼🪘🎤🥁🎸🪗🎺
N‘NU gbogbo ayida aiye
Ayo on wahala
lyin Olorun ni y'o ma
Wa l'enu mi titi
2. Em‘o yangan ti segun Re
Tit'awon t'eru npa
Y‘o fi mi se awokose
Ti banuje y‘o tan
3. Gbe Oluwa ga pelu mi
Ba mi gb'Oko Re ga
N'nu wahala. ‘gba mo kepe
O si yo mi kuro
🎹🎧🎼🪘🎤🥁🎺🎸🪗🎷
Okan mi yin Oluwa l'Ogo
Oba iyanu to wa mi ri
Ngo gb’agogo iyin y'aiye ka
Ngo fi iyin Atobiju han
Egbe: OIuwa 0pe ni fun O
Fun ore-ofe to fi pe mi
Jesu di mi mu titi, dopin
Ki nle joba pelu Re I'oke
🎹🪘🎤🎧🎼🥁🎷🎺🎸🪗
YIN Oluwa, enyin mimo
Awa ti je ni ‘gbese to?
Je k'a mu gbogbo ini wa
Wa pelu ayo
2. Jesu l'Oko t'o dara ju
O nfun wa l'okun l'oju ‘ja
Ibi kan ko le de ba wi
‘Gbat‘ a gbekele
3. Gbekele yin le, eyin mimoOlododo l’Olorun wa
Ko s'ohun to le, ya awon
T‘O fe l‘odo Re
🎹🎼🎧🎤🎷🪘
Fl iyin fun! Jesu, Olurapada wa
Ki aiye k'okiki ife Re nla
Fi iyin fun! enyin Angeli ologo
F'ola at‘ogo fun oruko Re
B'Olusaguntan, Jesu y'o to omo Re
L'apa Re lo ngbe won le lojojo
Enyin eniyan mimo ti ngb‘oke Sion
Fi iyin fun pelu orin ayo
🎹🎧🎤🪘🙏🥁🎷🎼
In nations all around the world, these are the kind of people you listen to if you want to know the direction a country is going.
You can't buy them, so you can't accuse them of being bought. They know what it means for an economy to be experiencing a turnaround...
Pat Utomi does not know because he is a theorist. If he's in the marketplace like Dangote, Elumelu, Adenuga, Rabiu, Otedola, etc he would know...
OLUWA l’Olus‘agutan mi
Emi k’o salani
O mu mi dubule ‘nu papa oko
Tutu minimini
Egbe: Awa dupe, at’ope da
Fun idasi Re fun wa
Larin Egbe Serafu
2. O mu mi lo si iha omi
Idake roro si de
O si tu okan mi lara
Ni ipa oruko Re
Egbe: Awa dupe...
🎹🎼🎧🎤🎷🥁🪘
Oba aiku, airi, orisun ogbon
T'O wa n'nu imole toju ko le wo
Olubukunjulo, Ologojulo
Alagbara, Olusegun, 'Wo la yin
Laisimi, laiduro, ni idakeje
O n joba lo, O ko si se alaini
Giga ni idajo Re bi oke nla
Ikuku Re b'isun ire at'ife
🎧🎹🎤🎷🎼🥁🪘
EJE ka jumo f’ope f'Olorun
Orin iyin, at'ope lo ye wa
Iyanu n'ife Re si gbogbo wa
E korin ‘yin s’Oba Olore wa
Egbe: Halleluyah Ogo ni fun Baba
A f'ijo, ilu yin Olorun wa
Alaye ni o yin O, bo ti ye
Halleluya! Ogo ni fun Baba
🎼🎧🎹🎤🎷
NDC gave non-indigenous people tickets in other states, except in the Southeast. What does that tell you?
Edo people don wake up from the gaslighting Wey IPOB people gaslight them in the last election.
A F‘OPE f‘Olorun
L'Okan ati Ohun wa
Eni ns'ohun ‘yanu
N'nu Eniti araiye nyo
Gbat' a wa l'om‘owo
On na l'o ntoju wa
O si nf’ebun ife
Se ‘toju wa sibe
2. Oba Onib’ore
Ma fi wa sile lailai
Ayo ti ko l'opin
On bukun y'o je tiwa
Pa wa mo n’nu ore
To wa gba ba damu
Yo wa ninu ibi
🎹🎤
OPE lo ye f’Olugbala
Iyin fun Metalokan
T’O da wa si d’ojo oni
A f'ogo f‘oruko Re
Egbe: Korin Ogo, Alleluya
Orin ogo lao ko
Korin Ogo, Alleluyah
Ko Hosannah s'Oba wa
2. Metalokan Oba Ogo
Baba fun wa l’agbara
F’awon asaju n’isegun
Fun won l’ogbon at’oye
Egbe: Korin Ogo...
🎹