@renoomokri Okunrin yi naa ni o tun gbe bi oro aje ile wa a se gbooro si s'ori ti o si nse gege bi awokose to dara.
Olorun oba a je ki o da fun o ju bayi lo, amin ๐.
I enjoy u always sir.
@renoomokri Iru eda eniyan to yato ti o si s'owon pupo ni ogbeni Reno Omokri yi je.
Oun nikan ni o ngba enu so fun ijoba apapo, oun nikan naa ni o np'arowa fun gbogbo omo Naijiria lati ma se ase mase.