Obì níí bi iku - Obì averts death
Obì níí bi àrùn -Obì averts sickness
Obì níí bi ọ̀fọ̀ - Obì averts losses
Obì níí bí ire - Obi births ire
Obì níí bí ọlá - Obi births honours
Obì níí bí ọlà -Obi births wealth
Obì níí bí èmi gígùn tíì san yà - Obi births long life and good health.
Ìsẹ́jú obì rèé
Kí ikú ma se sẹ́jú mọ́ wa
Kí àrùn máse sẹ́jú mọ́ wa
Kí ofo má ṣe seju mọ wá
Bí a bá da obì f'óòsà, ó ń yaan ni
Ọ̀rọ̀ wa yó yàn, yó yanjú láṣẹ Olódùmarè
Ayé wa kò ní dojúrú nínú oṣù tuntun yìí ooo....Àṣẹ Èdùmàrè 🙏🏿 🙏🏿 🙏🏿 🙏🏿
Happy New Month to us all 🥰🥰💙💙💃💃💃💃💃💃💃
Omo I suffer that year, Christianity really be aging you. Carrying Holy Ghost on my head, na craze I Dey craze.
Was 15 in the first picture the second I’m 18 and atheist.
Only for the transaction to be successful since last week and they fail to make my payment. Everything was cool until they quit responding to my dms with their claims that they can’t pay for the coin with cause they changed wallet.