Aṣiri o kin se ere mọ, Ó ti di Ipilẹ!!!
Ko kin se iroyin mon, wipe Mainnet Alpha ti bere lati ma ṣiṣẹ (ninu oṣu keji 2026)
Lati testnet lọsi amayederun iṣẹ ojukoroju, @Arcium ti gbera tan lori @solana
Igba akọkọ niyi ti kọmputa aṣiri rẹ ń ṣe iṣẹ agbara lati tan awọn ohun elo gidi lori mainnet
Ohun elo akọkọ ti o wa lori mainnet Arcium ni Umbra ton ṣiṣẹ ti o nfunni ni awọn iransẹ ni aabo ati paṣipaarọ ti o wa ni ipamọ
A tun le pe ni "ipo incognito" fun inawo ori-ẹrọ, bẹẹni wọn si gba ju $155 milionu ninu awọn adehun ICO nipasẹ MetaDAO (ọkan ninu awọn ti o tobi julọ lori solana) ti o si fihan ibere nla lati ọdọ awọn miran fun amayederun aṣiri
Awọn iṣẹ akanṣe miiran bii Melee, Vanish, ati Anonmesh n kọ awọn iyoku ni isopọ lori Arcium, lati le muu gboro si
Confidential SPL (ti atun lepe ni C-SPL) Ti C-SPL ba di ipegede ami, tabi itẹwọgba fun awọn token aṣiri lori Solana, eleyi maa mu lati jẹ igbesẹ pataki julọ fun aṣiri Solana
Ni kukuru, eleyi yoo mu ki gbogbo iṣẹ akanṣe ti o fẹ aṣiri, lati maa bọ lori amayedẹrun Arcium, fun kikọ orisiriisi iṣẹ akanṣe
Ìfihàn gbangba ti blockchain ṣẹda idena pataki fun gbigba jakejado fun gbogbo eniyan
Ni akoko AI tawa bayii, iran ti o han gbangba yii le yi awọn nẹtiwọọki di eto amojuto, ati fun awọn ọja inawo, o ṣafihan alaye ifura ti o ti ṣe idiwọ olu pataki lati gbe ori-ẹrọ, eyi to mu aṣiri ṣe pataki ju ti tẹlẹ lọ ni akoko ti awa bayi
Pẹlu Arcium, awọn isoro wọnyi di ohun igbagbe:
> Awọn ilana iṣowo di hihan gbangba
> Awọn gbigbe iṣura n mu itẹsiwaju ba ti iwaju wọn
> Awọn nkan olumulo wa ni ibiti ati le raye ri titi lailai
> Arcium gba awọn ohun elo laaye lati ṣe ilana awọn nkan olumulo lai ṣafihan rẹ
Ni akotan, gẹgẹ bi olori alasẹ Arcium, ọgbẹni @yrschrade ti sọ; wipe ibi ti a n lọ ni opin ohun gbogbo ni lati kọja aṣiri gẹgẹbi "pipa ohun nkan olumulo nikan mọn" lọsi ibi ti ati mari aṣiri gẹgẹbi ipilẹ apẹrẹ aiyipada fun gbogbo intanẹẹti, lati mu iyipada ba itan akọsilẹ
Kọmputa aṣiri tó lágbára jùlọ!!!
Hello X
I'm the founder of SLY MODE, a streetwear and sneaker plug based in Nigeria.
We sell 100% original designer clothing, sneakers and accessories.
No Fakes. No Compromise. Just Clean Pairs.
Follow for daily drops and streetwear content.
Ilorin is very close to Osun. Osun is 3 hrs away from Lagos. I just dey pity all of us mehnnn. So them go kill me because of allahu akbar? Omooo God abeg
A LETTER TO MALE GYNAECOLOGISTS: FROM A MALE GYNAE WHO HAS WORKED IN SAUDI ARABIA.
HOW TO EXAMINE WOMEN INCLUDING WOMEN ON HIJAB AND NIQAB.
And Then The Curtains Drew Close: A Woman, Her Body, and the Quiet Politics of Being Seen
Dear Anonymous Woman,
Asalamalekum,
And let me begin, as any honest storyteller should, by saying I am sorry, sorry that what should have been a moment of care became a moment of shock, sorry that the sacredness of your body met the unpreparedness of a system that should have known better.
Because, my dear, a vaginal examination is not merely a clinical act, it is a conversation between trust and tenderness, and it must never feel like an ambush. And you have every right to feel the way you do. And to the husbands, we know it isn't easy, so we carry you along, make you like a family.
And yet, here we are, living in a country where many still do not understand that Gynecology is not stumbled into, it is chosen, arduously, after years of exams, sleepless nights, and sacrifices that sometimes squeeze the soul dry. Many women, who must juggle motherhood and medicine, drift toward specialties with gentler hours, and so the corridors of Obstetrics and Gynecology continue to echo with the footsteps of men. We need more women in Obstetrics and Gynaecology!
And still, this is not an excuse, merely a truth that must sit beside your own truth.
Having worked in Saudi Arabia, a place where modesty is not merely culture but law, wrapped in hijab and niqab, I have seen how systems can be firm and gentle, strict and surprisingly accommodating. And so, walk with me through what should have happened to you, what could have protected your dignity.
You should have been told during antenatal visits that your care team might include male doctors. You should have been prepared, gently, so your heart would not leap in shock.
You should have been asked, not assumed. You should have been allowed to undress privately, with only a female chaperone beside you, holding dignity like one holds a fragile bowl of water. You should have been draped, covered first before anyone else entered.
And yes, you should have been given the simple, powerful gift of choice.
In Saudi Arabia, even with their stricter laws, male gynecologists thrive, not because women do not care, but because women are prepared. Because consent is not a whisper, it is a full sentence.
And here in Nigeria, our women deserve that too. They deserve education before examination. They deserve privacy before procedure. They deserve dignity, always.
My dear woman, your discomfort is not imaginary. It is valid and it is human.
And it is a reminder, a peeling back of the curtain, that our system must do better.
And so I say to our young women: step into Obstetrics and Gynecology if your spirit calls you. But come knowing that this path demands a piece of you, time, energy, and the soft ache of responsibility. For truly, uneasy lies the head that wears the crown.
Yet crowns must be worn by someone. And perhaps, by more women.