@DONJAZZY@TiwaSavage Baba don Jazzy, abeg make your love reach Ekiti too 🙏
I'm a fresh graduate and I sponsored myself to the uni. as I graduate finish make i cme dey work dey chop, my laptop spoil... The small one wey I dey manage, flood enter our house last month and spoil it
0237920616
WEMA
@DONJAZZY 0237920616
WEMA BANK
550k
Wanted to get another laptop. Flood entered our compound when I was away and my laptop was stopped working.
I'm a tech bro, and I've inspired more than 40 young people by teaching them minor tech skills for free.
today, we're launching the General Video Agent.
GVA edited this entire launch video. 👇🏽
public beta is now live at https://t.co/ivTRUHoVzE. no waitlist.
comment “GVA” for 1,000 free credits.
examples & capabilities in thread 🧵
Happy birthday, dear Àròjinlẹ̀,
You are an Òrìṣà, ẹni Orí ṣà dá ni ọ́.
May you toll this path of greatness till you fulfill your destiny
Ọ̀pẹ ya ṣẹ́rẹ́ṣẹ́rẹ́ kanlẹ̀
A dífá fúnwọn légùn Aré
Níbi wọ́n gbé ń fiwọ́n ré tantantan
A kìí fagbe ré, kágbe má lè kunṣọ rẹ̀ láró
Èdùmàrè jẹ́ n jíṣẹ́ tóo ránmi
A kìí fàlùkò ré, kálùkò má lè kunṣọ rẹ̀ lósùn
Èdùmàrè jẹ́ n jíṣẹ́ tóo ránmi
A kìí fi lèkélèké ré, kí lèkélèké má lè ki aṣọ rẹ̀ bẹfun
Èdùmàrè jẹ́ n jíṣẹ́ tóo ránmi
A kìí fi odídẹrẹ́ ré, kí odídẹrẹ́ má lè fi ìyẹ́ ìdíi ti bepo
Olódùmàrè jẹ́ n jíṣẹ́ tóo ránmi