Yoruba chants echoing through Rio Carnival! Paraíso do Tuiuti’s 2026 anthem "Lonã Ifá Lukumi" is a full-blown tribute to Ìṣẹ̀ṣe, Ọ̀rúnmìlà, and the resilience of Yoruba spirituality across the diaspora.
@FabrizioRomano@TheAthleticFC@ManUtd do really love this club why pochettino for good seak why you management don't deserve good things in life😡😡😡😡😡😡😡😡😡😡😡😡😡😡😡😡😡😡😡😡😡😡😡😡
Rubbish football club most disgraced football club in the world
in other words, he is richer than my husband.
the relationship was sincere, relationship built on lies and deceit.
you can't make this shit up story story how can a woman dating a married man in her husbands house think the married man will marry her stories 😒
Praying in Yoruba is a cheat code. You can’t approach God with this kind of praise, ask Him for a favour, and expect Him not to answer. Even God would be overwhelmed with joy if you entered His presence like this. 😄
Efi enu Tunmise
Enu ni abéré fi ń t��n așo șe
A kìí la pópó ká má kan ilé
A kìí là ộnà ká má kan ọjà
A kìí gbé àwòrán gàgàrà
Ká má fi ọwó rệ tì síbikan
A Dífá fún Yéwándé
Nígbà tó máa bí
Ó bí òwérę lómọ
Nígbà tó máa bí
Ó bí ògbàrá lómọ
Àwọn méjèèji sùn
Wộn forí lé elébútú
Wón pa elébútú ję òkú kìí wón lóde Òjòjò
Gbogbo eni tó bá ń pe orí mi níbi
Ikú oró ni kí wộn máa kú
Inú ògbàrá èjệ ni kí wộn máa sùn
Nítorí enikan kìí bá omi sộtá
Omi la bùwè
Omi la bù mu
Enikan kìí bá omi sộtá