Ohùn Àgbáyé jẹ́ àjọṣepọ̀ akọbúlọ́ọ̀gù káríayé tí ó ń ṣe ìtúmọ̀, ìkọ̀ròyìn lórí ọmọ-ìlú àgbáyé àti ìgbèjà búlọ́ọ̀gù. (@yobamoodua ni alákòóso) - darapọ̀ mọ́ wa.
Ẹ̀sún wẹ́ẹ́rẹ́wẹ́ ní í di ibú. Bí a bá rí tọ́rọ́ kọ́bọ̀ mélòó kan gbà jọ, yóò débìkan. Ẹ wá bá wa ṣe é, a ò lè dá a ṣe. Ẹ ṣàtìlẹ́yìn fún iṣẹ́ẹ wa.
https://t.co/oOTGmo5LYa
Ọ̀rọ̀ Ààbò Ẹ̀rọ-ayárabíàṣá ní èdè wa, àwọn Àbá láti ọwọ́ onígbèjà èdè Yorùbá lórí ẹ̀rọ-ayárabíàṣá ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
@yobamoodua@risingvoices@globalvoices@gvyoruba
https://t.co/cYy9boGkt1
Ọ̀rọ̀ Ààbò Ẹ̀rọ-ayárabíàṣá…ní èdè wa. Àwọn Àbá láti ọwọ́ Ọmọ Yoòbá (@yobamoodua) onígbèjà èdè Yorùbá lórí ẹ̀rọ-ayárabíàṣá ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà 👉🏿
https://t.co/gr0fJChQMU @risingvoices
Àǹfààní fún àwọn elédè Yorùbá ò tó nítorí kò sí àwọn ohun àmúlò ìdánilẹ́kọ̀ọ́ orí ẹ̀rọ-ayárabíàṣá wọ̀nyí ní èdè abínibí wọn, èyí tí ó dákun àìsí àṣà ààbò orí ẹ̀rọ-ayárabíàṣá tó péye láàárín àwùjọ náà.
https://t.co/qcRPCgmRtE
Àǹfààní fún àwọn elédè Yorùbá ò tó nítorí kò sí àwọn ohun àmúlò ìdánilẹ́kọ̀ọ́ orí ẹ̀rọ-ayárabíàṣá wọ̀nyí ní èdè abínibí wọn, èyí tí ó dákun àìsí àṣà ààbò orí ẹ̀rọ-ayárabíàṣá tó péye láàárín àwùjọ náà.
https://t.co/qcRPCgmRtE
“Orò ìjẹ̀bi àti ìtìjú” náà ni àwọn agbófinró orílẹ̀-èdè Russia pọwọ́lé lílò rẹ̀ láti fi “àbámọ̀” náà hàn ní gbangba àti ìpayà àwọn afẹ̀hónúhàn.
https://t.co/fG6rdW4I58
Níbi ìṣàpẹrẹ mìíràn, Ìmáàmù kan láti Ankara ṣàròyé pé àwọn obìnrin rí bí i "ẹran ní àwọn ìsọ̀ alápatà" bí wọ́n bá ń rìn kọjá ní títì.
https://t.co/eqL5J3qacM
Ìdílé Kútì tí ń fẹ̀hónúhàn nípasẹ̀ orin àti àwọn ọmọ Nigeria mìíràn tí wọ́n kọrin táko ẹlẹ́yàmẹ̀yà.
*Fẹ́mi àti Ṣeun Kútì mú kí orin Fẹlá wà láyé.
@Femiakuti@RealSeunKuti
https://t.co/CRyg1q7oCr
Olórin Calypso Trinidad àti Tobago, Black Stalin, àwòkọ́ṣe ‘ọkùnrin Caribbean,’ jáde láyé ní ẹni Ọdún 81.
Àwọn àgbá bọ̀ wọ́n ní tí àgbàlagbà bá kú, yóó dà bí ẹni pé ilé-ìkàwé kan ti jó lulẹ̀ ráúráú.
https://t.co/AOQ8YFxvzV
Fún Ayẹyẹ Àìsùn Ọdún Tuntun àwọn Ilé-Ìwé ní Moscow, àwọn orin kan ò bójúmu.
Wọ́n jẹ́ àwọn olórin tó ń bẹnu àtẹ́ lu ìkọlù orílẹ̀-èdè-Russia sí Ukraine.
#Odun#OdunTuntun2023
https://t.co/3YhtEdZPiD
"Mà á fẹ́ láti ṣàtẹnumọ́ pé àwọn tí kò nífọ̀n-léèékánná lọ̀pọ̀ àwọn olùfaragbá ìyà àwọn ológun, èyí tí ó sì ń tẹ̀síwajú." - Kubota Toru
#Myanmar
https://t.co/v4DpjNFydW
Ọ̀rọ̀ Ààbò Ẹ̀rọ-ayárabíàṣá…ní èdè wa. Àwọn Àbá láti ọwọ́ onígbèjà èdè Yorùbá lórí ẹ̀rọ-ayárabíàṣá ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà @risingvoices@yobamoodua#DigitalSecurity#Yoruba
https://t.co/gr0fJChQMU
Láago 3 ọ̀sán òní, èmi àti àwọn ẹlẹgbẹ́ mi láti Global Voices yóò máa fọ̀rọ̀jomitooro ọ̀rọ̀ lórí "iṣẹ́ ògbufọ̀ àti títú ìmọ̀ ọ̀rọ̀ láti èdè kan sí òmíràn gẹ́gẹ́ bí ìjìjàǹgbara orí ẹ̀rọ-ayárabíàṣá".
Ẹ darapọ̀ mọ́ wa. #itd2022#GV
https://t.co/R7TUaWRD3T
Ìròyìn yìí jẹ́ ara Ohùn-kẹ́lẹ́kẹ́lẹ́, tí í ṣe ìwé ìròyìn Civic Media Observatory ti Ohùn Àgbáyé.
https://t.co/9Cu2DB3tJ0
#OhunAgbaye#GlobalVoices#Yoruba
Ẹ kú sànmánì yìí o ẹ̀yin olùkù mi.
My people, I hail you. Trust your weekend is going well.
It's still your host, Ọmọ Yoòbá @yobamoodua. Today, I shall be exhibiting some of the infinitesimal #Yorùbá axioms; the 🐎of words 4 ur reading pleasure and learning. #proverbs
Ọdún kẹta rè é, ìwà ata ò yí padà, níṣe ni ó ń gbóná sí i. Ní ọ̀la yìí, èmi kiní yìí yóò máa gba ìṣàmúlò @DigiAfricanLang lò, tí n ó sì máa fi àdàmọ̀dì Gẹ̀ẹ́sì tòun Yoòbá sọ omi t'ó wà lámù fún èdè Yorùbá ní ọjọ́ iwájú. Eré gbogbo di ọ̀la. Ire o! Ire kàbìtì!
À ń wá ògìdìgbó agbédègbẹyọ̀ ènìyàn bíi ọgọ́rùn-ún fún èdè kọ̀ọ̀kan (Haúsá, Ígbò àti Yorùbá) tí yóò bá wa ṣe iṣẹ́ ògbufọ̀ tí yóò sì gba owó ọ̀yà lẹ́yìn gbèdéke ọ̀sẹ̀ kan àṣeparí iṣẹ́. Bí o bá fẹ́ di alábàáṣe, f'orúkọ kún 👉🏿https://t.co/RVUSDJo5Ju. Ire o!
Ọlọ́pàá Orílẹ̀-èdè Indonesia mú akẹ́kọ̀ọ́ mẹ́fà tí ó na àsíá ‘Àyájọ́ òmìnira orílẹ̀-èdè Papua’ tí a gbẹ́sẹ̀lé sókè.
#Papua#PapuaIndonesia
https://t.co/WCWDHNpzOd