Top Tweets for #iwure
Olódùmarè, Orísun gbogbo agbára, a bẹ̀ ọ lónìí:
Kí o bù kún iṣẹ́ ọwọ́ wa
Kí o yọ gbogbo ìdènà kúrò lójú ọ̀nà wa
Kí ayé wa kún fún àlàáfíà, ìlera àti ìbùkún.
Kí a ṣe àṣeyọrí.
Àṣẹ.
Tí o bá gbà, kọ “Àṣẹ” sí Àríwísí 👇
#EdeYorubadunlenu #iwure #yoruba #prayerworks

#EdeYorubadunlenu pẹ̀lú ÌWÚRE fún ỌJỌ́ ỌJỌ́BỌ̀
IWÚRE ỌJỌ́BỌ̀:
O kò ní rí ìfàsẹ́yìn mọ́ nínú ayé rẹ. Wàá di ẹni tí ń tẹ̀síwájú níbi tí o ti kùnà tẹ́lẹ̀ rí. Kò ní sí ìdíwọ́ kankan mọ́ ní iwájú rẹ.
#Yorubaprayers #Yorubaculture #YorubaLanguage #Iwure #prayer

#EdeYorubadunlenu pẹ̀lú ÌWÚRE fún ỌJỌ́ AJÉ 👇
Lọ́lá Olódùmarè Ọba tò layé; Ọba tó ti ń bẹ kayé ó tó máa bẹ, Èdè Yórùbá ó ní kú
Bẹ́ẹ̀ ni kò ní dohun àtẹ̀mẹ́rẹ̀.
Ẹ jẹ ká ṣe ipa tiwa,
Ká sa gbogbo ipá tiwa,
Ká fèyí tó kù sọ́wọ́ Elédùwá!
#Iwure #prayerworks

LÓNÌÍ ỌJỌ́ AJÉ, Ẹ ṢE ÀṢẸ!!!
A kú àmójúbà oṣù tuntun o
#yoruba #yorubanimi #yorubaculture #oseyifunmialarofo #explorepage #reels #explore #prayer #iwure #monday
ÌWÚRE ỌJỌ́ ỌJỌ́RÚ
🙏
Lónìí Ọjọ́ Ọjọ́rú,
Ibi òní ru bò wá,
Ire lá ru bò wá,
Orí wa òní burú,
Ẹlẹ́dàá wa òní dàrú,
Oníṣẹ́ ayọ̀ á jẹ́ fún wa,
Aó gba lẹ́tà ayọ̀ kà l'ásẹ Èdùmàrè.
Àṣẹ wàáà
#Iwure #Yorubadun #AsaYoruba
"Orí jàre filée mi bùn mi,
Orí jọ̀wọ́, jàre fọ̀nà mi bùn mi,
Fiṣẹ́ mi yìn mí,
Fọ̀wọ̀ wọ́ mí lóko lódò,
Orí pẹ̀lẹ́ o,
Abániwáyé má ṣe é gbàgbé..
Orí ni à á fi ṣòwò àṣejèrè,
Orí mi wá gbére kò mí
Yà mí ya ibi"
#YorubaBooks #Atelewobooks #Iwure
© @egbeatelewo
"Orí jàre filée mi bùn mi,
Orí jọ̀wọ́, jàre fọ̀nà mi bùn mi,
Fiṣẹ́ mi yìn mí,
Fọ̀wọ̀ wọ́ mí lóko lódò,
Orí pẹ̀lẹ́ o,
Abániwáyé má ṣe é gbàgbé..
Orí ni à á fi ṣòwò àṣejèrè,
Orí mi wá gbére kò mí
Yà mí ya ibi"
#Atelewo #Yoruba #YorubaBooks #Atelewobooks #Iwure

Ojúmọ́ ire gbogbo fún olúkúlùkù.
His imperial Grace, OOO Dada (Obalesun Ọbàtálá and Ọlọja of Iranje) says ìwúre (prayers) for yorùbá descent and Nigerians at large.
If you're a pregnant mother, you should watch this.
Happy Obatala worship day
🤍✨🐘🐚
#prayers #iwure #obatala #obalesun #ileife #yoruba #nigeria #iwure #friday #culture #spirituality
Ojúmọ́ ire and grand rising to the Yoruba / Africans descends across the globe.
May the blessings of Ẹ̀YỌ̀ be ours, and curses to our foes.
Enjoy your weekend
#Eyo #iwure blessings #prayers #Grandrising #ojúmọ́ire #IgboreAbeokuta #Abeokuta #Egba #Tayeoriṣa #yoruba
Ìwọ ọmọ yìí o ó gbò ó,
O ó tọ̀ ọ́,
O ò ní dàgbà ìyà,
O ò ní dàgbà danidání,
O ò ní dàgbà ìyà,
O ó fọwọ́ pá ewú,
O ò ní fọ̀pá tẹlẹ̀ níbùjẹ àìríṣe,...
Ayé re yóò kún fún ayọ̀,
Ayé re yóò kún fún ire.
#Atelewo #Yoruba #YorubaBooks #Atelewobooks #Iwure #AdebayoAyelaagbe

#Iwure
To All Sons & Daughters of Oodua Race Round the World 🌎 May OLODUMARE Always be our Guardians in all our Endeavor.
ASE 🙏❤️
@ThinkYoruba_1st
@lagospedia
@Olamirewaju22
@adeoluorisa
@tyewoolove
@blockofbuilder
@YOLICOM6
@OmoObaAlewi
@animolenikun
#Yorubatotheworld
Last Seen Hashtags on Sotwe
Trends for you
Most Popular Users

Elon Musk 
@elonmusk
240.9M followers

Barack Obama 
@barackobama
118.8M followers

Cristiano Ronaldo 
@cristiano
114.5M followers

Donald J. Trump 
@realdonaldtrump
111.9M followers

Narendra Modi 
@narendramodi
107M followers

Rihanna 
@rihanna
98.7M followers

NASA 
@nasa
92.2M followers

Justin Bieber 
@justinbieber
91.8M followers

KATY PERRY 
@katyperry
90M followers

Taylor Swift 
@taylorswift13
84M followers

Lady Gaga 
@ladygaga
75.5M followers

Virat Kohli 
@imvkohli
73.4M followers

Kim Kardashian 
@kimkardashian
70.8M followers

YouTube 
@youtube
68.7M followers

Neymar Jr 
@neymarjr
66.4M followers

Bill Gates 
@billgates
65.2M followers

Selena Gomez 
@selenagomez
63.1M followers

The Ellen Show
@theellenshow
62.2M followers

CNN 
@cnn
61.7M followers

X 
@x
60.6M followers













