@MrCharlesky Good day Mr Charles
I’m Huldah Shado, a Customer Service Representative skilled in communication, problem solving, and customer support. I’m passionate about delivering excellent service and ensuring customer satisfaction. I would love the opportunity to contribute to your team.
Ìlérí ayọ̀ yóò ṣe mọ́ mi lára,
mi ò ní ṣògo nù,èmi ni màá bọ̀rí ogun, ọfà ìkà ò ní bà mí.
Àwọn tó dìtẹ̀ ogo mi, yóò pàrẹ́ bí ìsò,
àwọn tó ṣọ́ ìṣìṣe mi fún ìbì, wọ́n a rìn fèsè kọ́,
mi ò ní sàkóbátá fún ẹ̀gbẹ́, ayé yóò kí mi pé “kú oríire.”
Ní Ọdún yìí, màá rọ́wọ́ mú,
màá rí t’ẹ́mi ṣe, ọ̀nà àlà fún mi.
Màá bọ̀rí ogun, màá gbé orúkọ ọ̀gọ́ dórí,
àbánigbẹ̀rù ayànmọ́ yóò wá mi rí.
Angẹli Olóórè yóò wà pẹ̀lú mi,
èrù ògo mi ò ní dànù,
ní gbogbo ọ̀nà, ọkàn mi yóò balẹ̀,
ìjàkùlẹ̀ yóò kúrò ní ọ̀nà mi.
Adínilówó yóò kúrò lọ́na mi,
èpè ìdílé yóò pare lórí mi,
ìbí tí mo bá fẹsẹ̀ tẹ̀, a ó gbà á fún mi,
ọ̀gọ́ mi yóò yọ̀ títún.
Ọkàn mi yóò balẹ̀ ṣe, mi ò ní kú ní rẹ̀wẹ̀rẹ̀,
ohun tí mi ò rò, kò ní bà ohun tí mo rò jẹ́,
ohun tí ń bá dáwọ́lé yóò ṣe rere.
The "Kindly find attached" that will enter your inbox this week will be;
Job Offer.
Promotion Letter.
Bonus Approved.
VISA Approved.
Scholarship Granted.
AMEN!!!