Ọpé lówó Ọlóhun Oba àti gbogbo àwon ènìyàn mi tíwón dúró tìmí láti ìbèrè odún yii wá pèlú pèlú gbogbo rògbòdìyàn àti ìdààmú lotun lósì esé o, aó jọ pé fúnra wa o, ojú òní tìyín o, .MOKÍ ARA MI KÚ ỌJÓ ÌBÍ ÒNÍ ooo🎂❣. èmí gígùn àti ìfòkànbalè kí Olúwa o fifún mi àti ìdílé mi🙏🏾
2. you have ever been a blessing to my life and you are the best thing that has ever happend to me in my entire life because of the priceless gifts you gave me, you were my back bone ,you are a warrior that even fought for your life till the point of death💔😭