@OsunDefender Ọjọ́ óríadé bá ti fadé dójúgun, ni fìlá ń gbayì tálápòólà orí náà a sì dẹni ayé yẹ.
Ẹ̀bi fìlà kọ́, ẹ̀bi olórí pọndanran sì kọ́, ẹbi ẹni a fadé dé lórí tó sọ̀ ọ́ dẹrù orúnkún ni.
Ó gbọgbọ́n o, bẹ́ẹ̀ ló gbẹ̀sọ̀.
Ẹ kú dédé ojúmọ́ o.
Ẹ tún bá wa gbé òwe yìí yẹ̀wò, bóyá ó ṣe é tẹ́wọ́ gbà
Watchout for a monologue on this on Olusam Babs platforms.
#olusambabs#yoruba@ThinkYoruba_1st
@NTANewsNow Still trying to figure out how the governor will be able give an accurate and strategic report without being flanked by Security expert.
Will the meeting be a sort of 'àwọn àdúgbò yẹn ò jìnà síra wọn', 'ṣe lẹ̀jẹ̀ ń sàn' or what.
I believe perimeter and Intels are key.
To gbogbo àgba Yorùbá feeding our oríadés with cultural accounts,
° can we please add that Oríadé kì í hùwà bí ẹrú? and that Oríadé kì í sọ ni dalárìífin.
Privilege shouldn't be regarded as immortality... Àgbà làgbà yóò máa jẹ́, àpọ́nlé sì loúnjẹ́ àgbà.
Yorùbá Ronú!!!
Again, another ìkùnsínú seems to be brewing between Oríadé méjì within ilẹ̀ kóòótù-o-ò-jíire.
Although I saw the short clip, it may be important to get the full clip in order to see what happened between the two monarchs after the recorded and trimmed part.
On the part of Aláàfin,
° would stretching his ìrùkẹ̀rẹ̀ instead of barehand not be better if at all his refusal to stand is somewhat being tied to cultural demand as being pushed around?
° why is he being in the news for the same reason against different oríadés?
Our final outing of 2025 was #Ereya2025, hosted by @_oneyorubagirl 🧡
Pure Yoruba fun games, culture, and real community building.
Big thank you to all Yoruba content creators!
@tyewoolove@olusam_babs
Ẹlẹ́ja kẹ́fí ekú ní bèbè ẹja, ó ránṣẹ́ pológìní. Ẹ gbọ́, bólógìní bá peku tán, ìgbàwo gan-an ni kò ní fàbọ̀ bẹ́ja?
Àt'eku, Àt'ológiní, kò sẹ́ní fojúure wẹja o, orí ẹja nìkan ló le gbẹja.
Only God can safe the masses...Ó gbọgbọ́n o bẹ́ẹ̀ ló gbẹ̀sọ̀!
#Trump
@gtbank what's going on? Being expecting a fund transfer since morning. Meanwhile, the sender's bank has already tagged the transfer to be successful.
The inconvenience is becoming unbearable!!!
Ẹ̀yin ará ìkànnì ìbánidọ́rẹ̀ẹ́ onígbégilégi yìí, wọ́n lónìí l'ẹ fi ń sàyájọ́ èdè Yorùbá sísọ lórí ìkànnì yìí.
Ibo gan-an ni k'á ti bẹ̀rẹ̀ báyìí?
#yorubadun#YORUBADAY#Yoruba