BIGGER THAN AFRICA IS COMING TO PBS
We’re honored to share that Bigger Than Africa has been acquired by American Public Television (APT) for national broadcast on PBS member stations.
Black History Month, February 2026, reaching over 130 million https://t.co/9l07sG7toL
ÌKÌLỌ̀ PÀTÀKÌ:
Ẹ má da àwọn ohun à mú ṣẹ agbára yín nù nítorí ẹ̀sìn àjòjì.
Àfọ̀njá, Ààrẹ Ọ̀nà Kakanfò ṣe bẹ́ẹ̀ níjọ́sí ọwọ́ àwọn Fulani tẹ̀ẹ́.
Ẹ má jẹ́ kí wọ́n ó fi ẹ̀sìn wọn pẹ̀lú ẹ̀ tàn jẹ gba agbára ní ọwọ́ yín kii wọn ó lè sọ yín di ẹrú wọn.
Amúnisìn ni wọ́n.
Ẹ má jẹ̀ẹ́ kii wọn ó mu yín sìn
#yorubaculture #yoruba #ifa
It's the agenda of Ibadan indegenes reason they were campaigning for Ibadan State, the throne of Alaafin is too much for them to handle, now it's subjugation of the throne.
Ori Ade ko ni fun won se.
If one parents, especially the mother are not culturally grounded, the successfulness of the children or child is limited and their happiness is hindered.
Yorùbá: Sí gbogbo ẹbí, ara, ọ̀rẹ́ àti ojúlùmọ̀ tí ẹ kí mi kú orí rere ti ọjọ́ ìbí, ẹ sẹun, modúpẹ́ púpọ̀. A ó ma rí ire bá ara wa se o.
Ọ̀yọ̀ a yọ ire gbogbo wá fún gbigbo wa. Àṣẹ
English: To every pedigree, relative, friend and well-wisher that sent their greetings/blessings/prayers on my birthday, much appreciation from me to you all.
Together we shall continue to celebrate great things in our lives.
Ọ̀yọ́ will draw all the great things of life to us. (So Mo It) Be)
On SUN DAY we worship the SUN in the morning at SUN RISE and in the evening at SUN SET.
Hail the SUN--the resurrection and the life NOT the son as they want you to believe.