Orí rere ni okùn ìwà
Adia fún Òrúnmìlà
Baba o mu Orí rere
La ìlú jà
Ebo ní kò yara mu şe
O gbebo nibe o rubo
N je gbogbo Iworosope
Bi e ba jí lowuro
E gbá Elédà yin my
Gbogbo Iworosope.
A kú ojúmó óò ojúmó ire gbogbo ló ma je fún wa óò
Ogeere jimoko, the priest in the city of
Idita
Cast Ifa for them in the city of Idita
When they were surrounded by attackers
They were advised to make ebo
They heeded to the advice
Ogerejimoko is a good Awo
One cannot cast Idingbe and die still
Happy ose Ifá
If you are still doubting the universalizability of Ifa, just listen to Òfún bàlà( Òfún Òbàrà)
Àdàbàkekelúke
Adífá fún Ifá
Ifá l'óun ó layé yìí já
Àdàbàkekelúke
Kò s'ílè t'á ò mo'fá
Àdàbàkekelúke( Name of sage)
Cast divination for Ifa
Ifa declares that it will rule the World
The Craziest thing about this is that ..90 % of the songs @Olamide performed here is in Yoruba. Like guy Yoruba for soldout concert !!!!! No features with any yankee artist oooo.
Omo I Stan a King 👑
Òyìnsèsè wáyé o
Ifá kóo wá fi mí joba o
Láwùjo ìlèkè ni Okún ti njoba
Òyìnsèsè wáyé o
Ifá kóo wá fi mí joba o
Ojú kìí pón eyinlà kó má là
Òyìnsèsè wáyé o
Ifá kóo wá fi mí joba o
Láwùjo ìlèkè lobìnrin ti nyan iyùn láàyò
Òyìnsèsè wáyé o
Ifá kóo wá fi mí joba o
We are starting the #CarpeDiemTour with the name of Allah the most beneficent and the most merciful , Bismillah , and InshaAllah at the end of the tour we will close with Alhamdulilah 🤲🏿 .... cc @Olamide@idjenimoney