Mo lọ sí kitchen lálẹ́ láti mu omi.
Nígbà tí mo dé, mo rí rice, stew, àti ẹran tó ń wo mí.
Omi náà kan sọ pé, “Ẹ̀gbọ́n, mo mọ̀ pé kì í ṣe mí ni o wá.” 😭😂
Some people follow you, like 3 tweets, make you think you've gained a loyal supporter…
Then disappear like a scholarship opportunity after you finally find the requirements. 😭