For me, I see it as a sacred moment – a time to pause, reflect, and set intentions for the year ahead. It is not about how many people wish me well, how many gifts I receive, or how grand the celebration is. Instead, it is about self-appreciation, gratitude, and self-love.
ASEJE OSHO BASIRI Tested okay ✅ ( 1am we dey eat ham)
House rent due
School fee and more
OKAN Elede
Eja aro
Ewe sawerepe
Ewe Ogo
Ewe Efo Gure
Ewe isaju
Ewe Efo Ebolo
Ataijosi 16
EPO
Iyo
Iyeere osun
SISE : ama ge OKAN yen si 4 , eja aro 4 , ama wa lo Awo ewe YII si lori , ama se lepo ni yo , ni ale , we go chop ham around 1am!
Password : Ama fi yere osun te : ODu Odi Meeji !
Ama so wipe ! Akesan dade owo , Aya re da oja x3 ………..:::::::::::: the full go be on space , see you on space Saturday by 9pm ! Be there
Note : we don’t eat till second day we chop this level , only gin we go drink till 7pm second day , if you can’t drink gin, dey alone with water or not eat anything
Don’t dm if you can’t come space !
ASEJẸ BASIRI TABI FUN OWO INAWO KIA KIA
Ewe laali
Ewe papasan
Iyere tabi Ata ijosi
Ẹ jẹ ki awọn eroja yi
Pọ daaadaa
Ẹ gun gbogbo rẹ papọ
Ko kunna daaadaa
Ẹ ko sinu ike funfun kan
Ẹ gbe pamọ bayẹn
Ti aba ti nilo owo
Ẹ ma bu niwọn
Ninu ẹtu asejẹ yi
Ẹ lọ ra
Ẹja arọ gbigbẹ nla 1 pere
Ẹ fise ẹja yẹn
Lepo niyọ
Ẹ se adua owo gidi si
Ẹ ko jẹ
Ba yi ni ẹ se ma jẹ
Asejẹ yi o.
ASEJẸ YI GBERA DAAADAA
KOJU BAYẸN LỌ IRE O ✌🏽🤍
#alburujy
#asiriogunibile
ASEJẸ ẸBẸ
Ile ẹyẹ ẹga to jabọ fun Rarẹ
Ẹ lọ poo mọ
Iyere tabi ata ijosi
Ẹran malu ekiri mẹsan
Ẹ fi iyereosun tẹ Ifa Eji Ogbe..
Ohun rẹ......
Siosio ẹyẹ ẹga Koto
Gbolohun kan ẹyẹ awọn Ajẹ
Oun Lodifa Fun Yeye Biwajọ Osoromoniga
Awọn Iya ke moo mi, moni
Ẹ ma ke mo ni moo,
Wọn ni nitori kinni, Monitori Ẹnu ti Ẹga bafi kole lo nfi ntu
Ẹ wa fi Ẹnu yin tu ọna owo ti ẹ di mọ mi silẹ fun mi
Ki ẹ si ma Royin mi si Rere Lati Oni loo...
Adura.
Ẹ wa dasi
Ẹ ro Papọ
Ẹ waa kojẹ
KOJU BAYẸN LỌ IRE O ✌🏽🤍
#alburujy
#asiriogunibile
#ifa
#isese
#YorubaSpirituality
ASEJE Asiri bibo
Itakun ewe ORIJIN die
Itakun ewe ajeobale die
Itakun ewe tude die
Grind everything with Iyere
Use it to cook one cat fish
Add salt and palm oil
When it is done say prayer and eat
Oshole Anu
Get ewe anu
Eye Leke Leke kan
Get on whole alligator pepper
Burn it
Mix it with soap
Break three native egg inside the soap
Get one IGBA oni Koko
Make hole on two it of it sides and put rope there
Put the soap inside the calabash and hang it up in a way that it will be dangling
Be bathing the soap every morning with prayer
IPARA ITAJA ATI ẸYỌNU
Amo ku idi siga 7
Ewe ọla niwọnba
Ẹ gun wọn papọ
Ko kunna daaadaa
Ẹ wa da sinu ipara Jet
Ẹ da Lọfinda bintu si
Ẹ po papọ daaadaaa
TABI
Ẹ da sinu ororo Goya onigo
Ẹ da Lọfinda bintu si
Ẹ po pọ daaadaa
Ẹ sẹ ipara tabi ororo
Inu igo yẹn ku ki inkan ti
A fẹ po papọ mọ le gba
Inu igo yi.
O yẹ ko ti ye wa bayẹn
Ẹ maa fi para jade
Ẹ sọra fun sina tori
Yio faa obinrin ati ọkunrin
Wa.
KOJU BAYẸN LỌ IRE O ✌🏽🤍
#alburujy
#asiriogunibile
#ifa
ASEJẸ AWURE OWO TO SARE SISẸ PAPAPA
Ẹ mu #1000 tabi #500
Lọ fi ja ewe sawerepepe
Ẹ lọ ewe ati owo ti ẹ fi ja
Papọ pẹlu ijọsi 16
Ko kunna daaadaa o
Ẹ fi se Pọnmọ tabi igbin
Tabi ẹran ẹlẹdẹ jẹ
Ẹ le pa gbogbo awọn
Ikan mẹtẹta yi papọ lati
Se asejẹ yi
Ẹ le pa meji papọ ninu
Awọn ẹran mẹtẹta yi
Lati fi se asejẹ yi
KOJU BAYẸN LỌ IRE O ✌🏽🤍
#alburujy
#asiriogunibile
ASEJE Ile Kiko
Ileke Itun
Ileke ifa
Abere die
Ileke iyun
Iye agbe 3
Iye aluko 3
Ikode 3
Omonigelegele die
Ewe ……….
Grind everything together and use it to cook one white dove that you cut into 16 places
The water you will use to cook it is Omi okun and Omi osa
You will combine the two
Before grinding it you will use that water to wash the grinder
Anything you want to wash for this work you will use that water
You will make one big osuka
And drop the soup on it once it is ready
If you want to build down stairs house you will sit on apoti to eat the concoction
If you want to build upstairs house
Eat it in the ceiling 😂
For the last part you know the drill I will forward it to your dm
Iba eyin agbalagba
ỌFẸ NI IGUN NJẸBỌ 🔥
Ori igun kan
Epo ọbọọ
Ẹ gun wọn papọ
Kunna daaadaaa
Ẹ wa po mọsẹ
Agbọ to gbo gidi
Omi inu rẹ lao fi po
Ọsẹ yi papọ daaaadaa
Ẹ wako Ọsẹ naa sinu
Epo agbọn yi naa
Ẹ mafi we.
ASIRI OLA RIRISE NIYI
ỌSẸ TO WỌNA GIDI
KOJU BAYẸN LỌ IRE O ✌🏽🤍
#alburujy
#asiriogunibile
ASEJẸ OWO KIAKIAA
Etigure
Ewe aanu
Ewe sawerepepe
Ewe tannagbowo
Ata ijosi 16
Ẹ lọ wọn papọ
Ẹ fi se igbin meji jẹ lepo ni yọ
KOJU BAYẸN LỌ IRE O ✌🏽🤍
#alburujy#asiriogunibile