So much joy and happiness seeing our parents playing football ❤️❤️😢😢
TG Omori Ramos #AlNassr Usky God of Tinubu Innoson Ikorodu Mohbad 2m Jagun Jagun Nice Brest Davido Khole Zlatan Malacia Burna boy #TOTLIV GOAT Sammy Larry kante Lamine Yamal Penalty Wike FC Barcelona #النصّر_الطائي Cristiano Ronaldo #BBNaijaAllStars 3rd of October Porto SevillaFunke Akindele #Balochistan Penaldo Buju BNXN Spartans #bbctq #49mOnBet9ja Cross #มินนี่ Thunder Abia state #GloAmbassador Antony Asake
North London forever
Whatever the weather, these streets are our own
And my heart will leave you, never
My blood will forever, run through the stone
#ARSMUN
Be there 😄
Gbógunmì…
“O pọ́n mi le, inú mi sì dùn sí ọ
Wò mí wò, un óò fún ọ lóògùn
Ogún ọdún ni mo gbé ní Ṣakí, kò kan t’ewé níní
Ọgbọ̀n oṣù ni mo lò ní ‘Jẹ̀bú, kò kan t’èpè
B’éèyàn ò bá t’orí ogun lọ, kò lè l’ẹyọ ataare kan
Èmi wá ‘lé ológun, mo kọ́’gun, mo k’óògùn
Mo!...
Wòó! Mo lóògùn o!
Òògùn burúkú nbẹ lọ́wọ́ mi!
Nílé ológun táa wà yí
Bí a bá yọ baba wa Ògúndìjì
Bá bá sì yọ ọwọ́ Agẹmọ
Láti ‘jọ́ tí wọ́n ti dá ilé ológun yìí ‘lẹ̀
Akọni bí èmi Gbógunmì ò sí
Èmi Gbógunmì
Ọmọ ogun
Ọmọ oògùn
Ọmọ Ògúnlágbẹ̀dẹ
Ọmọ agúnrin tún ‘rin rọ
Ọmọ arógun dìílẹ̀ bí iṣu…”