Eje kโa fโinu didun
Yin Oluwa Olore
Anu Re O wa titi
Lododo dajudaju
2. On nipa agbara Re
Fโimole sโaye titun
Anu Re, O wa titi
Lododo dajudaju
3. O mbo gbogbโeda โlaye
O npese fun aini won
Anu re, O wa titi
Lododo dajudaju
๐น๐ค๐ง๐ผ๐ฅ๐ช๐ท๐ช๐บ๐ธ
WA s'adura oro
Kunle k'a gbadura
Adura ni opa Kristiani
Lati b'Olorun rin
2. Losan, wole labe
Apat' aiyeraiye
Itura ojiji Re dun
Nigbat' orun ba mu
3. Je ki gbogbo ile
Wa gbadura l'ale
Ki ile wa di t'Olorun
Ati 'bode orun
๐น๐ผ๐ง๐ท๐ค๐ธ๐บ๐ช๐ฅ
JESU fe mi, mo mo be
Bibeli lโo so fun mi
Tire lโawon omode
Nwon ko lagbara, On ni
2. Jesu fe mi Enโto ku
Lati si orun sile
Yio we ese mi nu
Jeki omo Re wole
3. Jesu fe mi sibe si
Bi emi tile sโaisan
Lor'akete aisan ni
Yโo tโite Re wa so mi
๐น๐ผ๐ค๐ง๐ท๐ธ๐บ๐ฅ