Gbajúmọ̀ Olórin Fújì nnì, Táyé Adébísí, tọ́pọ̀lọpọ̀ mọ̀ sí Táyé Currency, tún ti fi ara rẹ̀ hàn gẹ́gẹ́ bíi....
https://t.co/LEIq25t1Uh
#jimike#Brymo#Northerners#hisenseindia
Ààrẹ ilẹ̀ America, Donald Trump, ti dúpẹ́ lọ́wọ́ Àjọ tó ń ṣe ìṣàkóso bọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá lóde àgbáyé, FIFA, fún bó ṣe bá agbọ́wọ́'wájú ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù oríléèdè rẹ̀, Fọlárìn...
https://t.co/EJRSY6HbYE
#Sammie#mohbad#DonaldTrump
Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Ṣèyí Mákindé, ti gbé òfin kónílé ó gbé ilé, o ní wákàtí mẹ́rìndínlógún kalẹ̀ láwọn ìjọba ìbílẹ̀ mẹ́wàá.......
https://t.co/dw9CRRML7A
#Oyo#VDM#Verydarkman#NigeriaPolitics
Ọnímọ̀kíkún nípa ẹ̀sìn Islam, Sheikh Ahmad Gumi, ti fajúro sí bí ìjọba àpapọ̀ ṣe ń pè àwọn agbébọn ní agbésùnmọ̀mí, pẹ̀lú ìkìlọ̀ pé ìgbésẹ̀ ọ̀hún leè mú kí ètò ààbò tí kò péye tó má a....
https://t.co/mHkcbQeKFA
#Midweek#Sammie#furry#Nigeria
Fọ́nrán tó ṣàfihàn gbajúgbajà aṣáájú ikọ̀ adìhàmọ́ragbẹ̀mí, Bello Turji, ló di tọ́rọ́fọ́nkálé lójú òpó ayélujára, níbi tí kònàǹkòrí agbésùnmọ̀mí ọ̀hún...
https://t.co/Vy7v03WMqn
#Fathersday#Jarvis#NigeriaPolitics#Nigeria
Ètò ìgbéyàwó alárinrin kan tó jẹ́ àrà ọ̀tọ̀ wáyé nílùú Ibadan, nípìnlẹ́ Ọ̀yọ́, níbi tí àwọn ìbejì lọ́kùnrin ti jọ gbé àwọn ìbejì lóbìnrin níyàwó...
https://t.co/DaTTpBXaY7
Àwùjọ àwọn èyà Fulani, lábẹ́ Ẹgbẹ́ àwọn ẹ̀yà Fulani tí ọ̀rọ̀ oríléèdè Nàìjíríà jẹ lógún, ti rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí Ààrẹ oríléèdè Nàìjíríà, Bọlá Tinúbú, àti Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Ṣèyí Mákindé, láti tọwọ́ Ajàjàgbara Yorùbá, Sunday Adéyẹmọ....
https://t.co/5gd3izHxRu
Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Ṣèyí Mákindé, ti túbọ̀ fi ìgbáradì hàn láti ṣe ìfararúbọ tàbí lo gbogbo ohun tó bá gbà láti fi gba àwọn akẹ́kọ̀ọ́ àti olùkọ́ tí àwọn agbébọn.....
https://t.co/fZRXlgtHOA
#Ronaldo#Festus#Mbappé#Oyo#Makinde
Ìròyìn jẹ́ kó di mímọ̀ pé ikọ̀ agbésùnmọ̀mí gbójúgbóyà débi pé wọ́n gbé òkú Ajagunfẹ̀yìntì Rabe Abubakar, lọ fún àwọn ẹbí rẹ̀ nípìnlẹ́ Katsina....
https://t.co/WXhpGZzYqt
#General#Katsina#Tiwa
Àgbà ọ̀jẹ̀ òṣèré nnì, tó tún jẹ́ ògbóǹkangí olùkọ́ni nípa eré orí ìtàgé, Olóyé Kọ́lá Gabriel Oyèwọ̀, ti jáde láyé, lẹ́ni ọgọ́rin ọdún......
https://t.co/QwNSbqR38y
#Matawalle#Generals
Ìjọba àpapọ̀ oríléèdè Nàìjíríà ti kéde ọjọ́rú, ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n ati ọjọ́bọ̀, ọjọ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kàrún-un ọdún ẹgbàá... https://t.co/LakMafrzc3
#Sallah #
Àwọn kan tí wọ́n fura sí gẹ́gẹ́ bíi ọmọ ẹlẹ́gbẹ́ òkùnkùn, ti yin ìbọn pa ẹnì kan tó jẹ́ oníṣòwò nǹkan ìpanu kan, Shawarma, tí wọ́n pe orúkọ rẹ̀ ní Andy.....
https://t.co/wxHvpwP3Q1
Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Ṣèyí Mákindé, ti jẹ́ kó di mímọ̀ pé ìṣàkóso òun kò ní jọ̀gọ̀ sílẹ̀ fún ìpániláyà tàbí ìdúnkokò... https://t.co/qS3kv8mk3w
#seyimakinde#OYO#Nigeria