Ààrẹ ilẹ̀ America, Donald Trump, ti dúpẹ́ lọ́wọ́ Àjọ tó ń ṣe ìṣàkóso bọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá lóde àgbáyé, FIFA, fún bó ṣe bá agbọ́wọ́'wájú ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù oríléèdè rẹ̀, Fọlárìn...
https://t.co/9Q16HMMUbW
Ìgbìmọ̀ aláṣẹ ìjọba àpapọ̀ oríléèdè Nàìjíríà ti fi ọwọ́ síi pé kí àtúnṣe tó lapájá bá ètò ìsìnrúlú àwọn àgùnbánirọ̀ lórílẹ̀èdè yìí, NYSC, èyí tí yóò jẹ́ àtúnṣe àkọ́kọ́ tó lapájá tí yóò bá ètò náà láti.....
https://t.co/1ZYI9GtBxA
Ọnímọ̀kíkún nípa ẹ̀sìn Islam, Sheikh Ahmad Gumi, ti fajúro sí bí ìjọba àpapọ̀ ṣe ń pè àwọn agbébọn ní agbésùnmọ̀mí, pẹ̀lú ìkìlọ̀ pé ìgbésẹ̀ ọ̀hún leè mú kí ètò ààbò tí kò péye tó má a....
https://t.co/mHkcbQeKFA
#Midweek#Sammie#furry#Nigeria
Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Ṣèyí Mákindé, ti gbé òfin kónílé ó gbé ilé, o ní wákàtí mẹ́rìndínlógún kalẹ̀ láwọn ìjọba ìbílẹ̀ mẹ́wàá.......
https://t.co/dw9CRRML7A
#Oyo#VDM#Verydarkman#NigeriaPolitics
Ọnímọ̀kíkún nípa ẹ̀sìn Islam, Sheikh Ahmad Gumi, ti fajúro sí bí ìjọba àpapọ̀ ṣe ń pè àwọn agbébọn ní agbésùnmọ̀mí, pẹ̀lú ìkìlọ̀ pé ìgbésẹ̀ ọ̀hún leè mú kí ètò ààbò tí kò péye tó má a....
https://t.co/GFlMPpeE6w
Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Ṣèyí Mákindé, ti gbé òfin kónílé ó gbé ilé, o ní wákàtí mẹ́rìndínlógún kalẹ̀ láwọn ìjọba ìbílẹ̀ mẹ́wàá.......
https://t.co/ZNP1SmGKxI
Fọ́nrán tó ṣàfihàn gbajúgbajà aṣáájú ikọ̀ adìhàmọ́ragbẹ̀mí, Bello Turji, ló di tọ́rọ́fọ́nkálé lójú òpó ayélujára, níbi tí kònàǹkòrí agbésùnmọ̀mí ọ̀hún...
https://t.co/Vy7v03WMqn
#Fathersday#Jarvis#NigeriaPolitics#Nigeria
Fọ́nrán tó ṣàfihàn gbajúgbajà aṣáájú ikọ̀ adìhàmọ́ragbẹ̀mí, Bello Turji, ló di tọ́rọ́fọ́nkálé lójú òpó ayélujára, níbi tí kònàǹkòrí agbésùnmọ̀mí ọ̀hún...
https://t.co/uPVuaRwZAG
Àwùjọ àwọn èyà Fulani, lábẹ́ Ẹgbẹ́ àwọn ẹ̀yà Fulani tí ọ̀rọ̀ oríléèdè Nàìjíríà jẹ lógún, ti rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí Ààrẹ oríléèdè Nàìjíríà, Bọlá Tinúbú, àti Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Ṣèyí Mákindé, láti tọwọ́ Ajàjàgbara Yorùbá, Sunday Adéyẹmọ....
https://t.co/5gd3izHxRu
Ètò ìgbéyàwó alárinrin kan tó jẹ́ àrà ọ̀tọ̀ wáyé nílùú Ibadan, nípìnlẹ́ Ọ̀yọ́, níbi tí àwọn ìbejì lọ́kùnrin ti jọ gbé àwọn ìbejì lóbìnrin níyàwó...
https://t.co/DaTTpBXaY7
Ètò ìgbéyàwó alárinrin kan tó jẹ́ àrà ọ̀tọ̀ wáyé nílùú Ibadan, nípìnlẹ́ Ọ̀yọ́, níbi tí àwọn ìbejì lọ́kùnrin ti jọ gbé àwọn ìbejì lóbìnrin níyàwó...
https://t.co/luGked2T6w
Àwùjọ àwọn èyà Fulani, lábẹ́ Ẹgbẹ́ àwọn ẹ̀yà Fulani tí ọ̀rọ̀ oríléèdè Nàìjíríà jẹ lógún, ti rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí Ààrẹ oríléèdè Nàìjíríà, Bọlá Tinúbú, àti Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Ṣèyí Mákindé, láti tọwọ́ Ajàjàgbara Yorùbá, Sunday .....
https://t.co/W6k2TGsuzc
Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Ṣèyí Mákindé, ti túbọ̀ fi ìgbáradì hàn láti ṣe ìfararúbọ tàbí lo gbogbo ohun tó bá gbà láti fi gba àwọn akẹ́kọ̀ọ́ àti olùkọ́ tí àwọn agbébọn.....
https://t.co/fZRXlgtHOA
#Ronaldo#Festus#Mbappé#Oyo#Makinde
Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Ṣèyí Mákindé, ti túbọ̀ fi ìgbáradì hàn láti ṣe ìfararúbọ tàbí lo gbogbo ohun tó bá gbà láti fi gba àwọn akẹ́kọ̀ọ́ àti olùkọ́ tí àwọn agbébọn.....
https://t.co/ziSf8gHpCk