@instablog9ja @EndSWATHQ That why we educate people about blockchain through 'INKSNATION"which can pay off Nigeria debt between two weeks so we beg Nigeria government to embrace it but they insist because of their greediness and selfishness and is an Nigeria citizen who brought this huge opportunity!
OGUN GIRI (CONVULSION OMODE ATI AGBALAGBA)
Ewe kataba tutu die, alubosa elewe pupo, a o ge si kekeeke, a o fi oronro maalu pupo re eroja naa fun (3 days). Omode yi o maa lo sibi kan lojumo, agba yi o maa lo sibi meji.
EYONU ASINA OWO ( 3in1)
Retweet for others to benefit
Dm if you need
AKo alagba kan
Abo alagba kan
EPO obo
Eru Alamo
Abeere ( needle) 32
Igba Aje
Owo eyo 8
Ose
SISE : ama gun awon Eroja yii , Alagba , epo obo , eru lamo , ti aba gun tan , ama wa fi Owo eyo te iga Ejiogbe , ama fi abeere 32 gun Lori round , ama de pa, am wa gbe pamo , leyin 3 days odi wiwe no Araro !
Dm if you need
ASIRI TIRA IFERAN TI A FI N SO EYAN MEJI PAPO TO DAMILOJU TI KO SI NI ASADANU NINU
GARI TIRA YI - Ewe amunimuye ati kafura pelebe.
A o lo gari tira ti e n wo picture re yi papo kunna daada, a o ku si oju tira inu photo yen, a o we ni ikobere ni ona meji;
1/2
ASIRI IJINLE TI A FI N WO ENI TO YA WERE TABI WERE TO TI N BUGI JE SAN.
EROJA RE
Ewe odan to jabo sile funra re (mesan fun okunrin, meje fun obinrin
Ako alangba ooye kan (abo fun obinrin)
Ewe oparun tutu to po die
Okan elede tutu ti ko wo omi oojo
1/3
ÀSÍRÍ OSE ATÚDÈ, ÀMÚBÓ ÀTI ÌKÓRIRA TO CONFIRM 💯✅
A maa gun eso aworoso eyo mokanla pèlú tewe tegbo tude ati eepo obo to finmu, a o lo kúná papò daada, a o fi omi agbon po papò mose èyí tí o ba wu wa, a o ko sinu igba tabi ike funfun onideri.
LILO RE 👇
ISEGUN OTA TODAJU 💯
Ori eran etu kan
Ori aparo kan
Odidi atare kan
Ori igbale
A o jo gbogbo re papo, a o lo kunna daada, a o maa fi fo eko tutu mu ninu omori igba pelu pipe gbolohun re
GBOLOHUN RE 👇
OSO AGBARA FIDIPOTE
E ba mi wa agbebo pepeiye kan, ki e du sinu agbada ijogun, a o la pepeiye naa laya pelu blade tuntun kan, a o fi eiyele funfun ooye kan si ninu, pelu eiye ega ako olori dudu meta, ati eso laa pupa lopolopo, eru alamo, odidi atare meta ati kerewu to po.
1/2
OSE OSO OWO TO JINA GIDI 1000%✅
Ori oka kan
Ori odidere kan
Ori agbe kan
Ori aluko kan
Ewe ajeobale tutu
Ewe orijin tutu
Oga ooye kan
Ileke itun
Ileke ifa
Abeere
Aso funfun opa kan
A o gun gbogbo re papo mose dudu, a o wa kan apoti kekere kan.
1/2
ÀÁJO ỌSẸ AWENU TO NI AGBARA FUN ẸNI TI NKAN KO LO DEEDE FUN
E ba mi wa eepo obo to fin daada ki e ba mi gun kùnnà daada loto, e tun ba mi wa eja ojiji ooye kan, a o gun kunna daada loto naa, a o wa da ewe akoko oojọ sii, a o gùn kùnnà daada.
1/3
ONA ABAYO BI AYE BA DE EEYAN MOLE TI KO SI ATUNSE KANKAN
Odidi ooye okete kan, a o gun ninu odo pelu ata ijosi die, eepo obo die, igi nla die, ewe orijin die pelu ose dudu
A o maa we ninu ajadi apeere laiwo bata fun ojo meje pelu omi to lo woorowo.
O daju !
OGUN ATEPA ( make we no step on jazz)
Retweet for others to benefit
Surveyors
Market place
Family house
Farming
And more
Dm if you need it
Elo wa Ekuro Oju Ona 9
Eyo Atare 9
Ewe Seyo ti ko lu ju , 9
SISE: Ema jo papo, E ma fi sin gbere round orun Ese yin mejeeji
ATEPA NI ! Ki Ema te nkan mo le NINU Oko
For mercy
Get ogede Omini 3 ( 3 native banana)
Get eru Alamo
Get 3 native egg
Get OSE Ghana
Get gin ( schinapp)
Peal the banana ,
pound it with the eru Alamo , break the three eggs in it and dispose its shell
Then mix the white OSE Ghana with it
Then use the schinap gin to mix it well
Be bathing the soap every morning
Retweet for more tips
ASEJE ASHiNA
1 ESO bomubomu ojor ( sodom apple plucked the same day )
Ata ijosi 16
Grind it together .
Get Edo malu ( cow liver ) cut into 16
Use what you grinded to cook the Edo malu add salt and palm oil .
Once it is done , say prayers and eat .
IJINLE ASIRI AGBARA OSHOLE TODAJU 💯
Odidi ori oka kan
Ori ere kan
Ori ahun kan
Ewe akoko
A o gun gbogbo re papo mo ose dudu, a o wa ko sinu igba onikoko, a o de pa fun ojo meje.
Leyin ojo keje, a o maa fi kainkain ibile we.
A o maa ri owo gidi gba.
ASIRI ONA ABAYO SI PROMISE AND FAIL ATI IKORIRA TODAJU 💯
Eepo obo to finmu
Ewe obiba oojo
Ewe orijin oojo
A o gun gbogbo re papo mose dudu, a o fi bintu igo meta po papo; a o lo mu ese ina kan, a o ju sinu ose naa, a o tun gun papo mora won.
A o maa we ose yi ni gbogbo igba.
ASIRI OSE IKORIRA TODAJU
Ifun ako ati abo alangba
Ifun eyele eyikeyi
Ewe orijin tutu
Ewe awerepepe tutu
Ewe rekureku
Eepo obo
Egbo tude
Eru alamo.
A o gun gbogbo re papo mo ose, a o ko sinu ike funfun, a o maa we ni gbogbo igba.