@alat_ng Are you honest with the rates? On my ALAT goals, I observed in the last 3 days, you have unilaterally reduced the daily interest paid. How do you explain this?
@yoruba_proverbs Ẹ ẹ̀ ríi. Wọ́n ní k'árúgbó gb'ọ́mọ dání, ó l'òun ò l'éhín, ṣé wọ́n ní k'ó g'ọ́mọ jẹ ni? Tótó o!
Can you see it. They ask an elderly woman to help carry a child, she said she has no teeth, did they ask her to bite the child? Respect to the elders!
@yoruba_proverbs Ẹ ẹ̀ ríi. Wọ́n ní k'árúgbó gb'ọ́mọ dání, ó l'òun ò l'éhín, ṣé wọ́n ní k'ó g'ọ́mọ jẹ ni? Tótó o!
Can you see it. They ask an elderly woman to help carry a child, she said she has no teeth, did they ask her to bite the child? Respect to the elders!
@yoruba_proverbs ṣùgbọ́n, ọ̀tún wẹ̀'sì òsì wẹ̀'tún l'ọwọ́ fi ń mọ́ o. Tótó o ṣe bí òwe o.
The right hand washes the left, and the left hand washes the right, that's what makes the hands clean
@yoruba_proverbs Hnmm. A à kìí sun ún, a à kìí sè é, bẹ́ẹ̀ sì ni, a kò gbọ́dọ̀ ṣàìjẹ́ ká kúrò nídìí rẹ̀. Tótó, ó ṣe bí òwe o.
You must not roast it, you must not boil it, and you must not leave without eating it
@yoruba_proverbs Bẹ́ẹ̀ni o. Wọ́n ní kò sí'rú ìfun tí ń bẹ nínú òrò adìyẹ tí àṣá ò mọ̀.
There is no type of intestine inside the baby hen that the eagle does not know about
@yoruba_proverbs Wón ní obìnrin sọ̀'wà nù, ó l'óun ò l'órí ọkọ; kíni wón fi ń gbé'lé ọkọ bí kì í ṣe' wà
A woman lost manners, she is complaining she doesn't have the luck of husband; but what does a woman need to live with man if not manners
@yoruba_proverbs Àmọ́, ikán parapọ̀, wọn a kọ́'lé ńlá-ńlá, anìnkànrìn l'ó j'ọmọ ejò níyà.
Tótó o.
Termites come together, they build big houses; walking alone is what sets the snake back
@yoruba_proverbs Bẹ́ẹ̀ni o.
Wọ́n tún ní bí'ná bá ń jó ló'ko, á b'ọ̀wọ̀ fún'rèké. Tótó ó ṣe bí òwe o.
No matter the fire in the plantation, it must respect the sugar cane. Respect to my elders
@yoruba_proverbs Bẹ́ẹ̀ni o.
Kò sí irú ìfun tó wà nínú ìròmadìyẹ tí àṣá ò mọ̀.
There is no type of intestine inside the baby hen that the eagle does not know
@yoruba_proverbs Bí a bá wá f'ẹyin sẹ́'yìn ọwọ́, tí a fẹ̀' yìn rìn dé'lú Ìs���́yìn, ẹni tí a yin' ni lá yin'ni; ẹni tí ó sì ní yin'nii, kò ní yín'ni
If one places an egg at the back of one's palm and walk with his back to the city of Ìsẹ́yìn, not everyone will appreciate it
@yoruba_proverbs Ọmọ atiro tó lọ ra bàtà ẹsẹ̀ kan, ọ̀rọ̀kọ́rọ̀ l'ó fẹ́ gbọ́.
The child of an handicapped that went to buy shoe for only leg, he will hear his history.