ASIRI PERFUME IBUKUN TODAJU ๐ฏโ
lleke itun 16
lleke ifa 16
Abeere 16
Sawerepepe gbigbe die
Ewe ola die.
A o lo gbogbo re papo, a o daa si inu perfume to ba wu wa, a o maa fi sara jade.
You all are trying to spoil my name, but you failed
Hypocrisy and manipulations everywhere
OGUN GIRI (CONVULSION OMODE ATI AGBALAGBA)
Ewe kataba tutu die, alubosa elewe pupo, a o ge si kekeeke, a o fi oronro maalu pupo re eroja naa fun (3 days). Omode yi o maa lo sibi kan lojumo, agba yi o maa lo sibi meji.
ASIRI IFA ITOJU ITO SUGAR TODAJU (DIABETES)
A o gba ito idi alaisan yi sinu koroba tabi basia kan, a o fi gbo ewe imi esu to maa ki daada; a o da sakiti re nu.
E maa bu fun alaisan diabetes yi mu loorekoore, kiakia ni alaafia maa de.
O daju bi iku se daju fun gbogbo eda eniyan
ASIRI IFA ITOJU ITO SUGAR TODAJU (DIABETES)
A o gba ito idi alaisan yi sinu koroba tabi basia kan, a o fi gbo ewe imi esu to maa ki daada; a o da sakiti re nu.
E maa bu fun alaisan diabetes yi mu loorekoore, kiakia ni alaafia maa de.
O daju bi iku se daju fun gbogbo eda eniyan
OGUN GIRI (CONVULSION OMODE ATI AGBALAGBA)
Ewe kataba tutu die, alubosa elewe pupo, a o ge si kekeeke, a o fi oronro maalu pupo re eroja naa fun (3 days). Omode yi o maa lo sibi kan lojumo, agba yi o maa lo sibi meji.
ASIRI TIRA IFERAN TI A FI N SO EYAN MEJI PAPO TO DAMILOJU TI KO SI NI ASADANU NINU
GARI TIRA YI - Ewe amunimuye ati kafura pelebe.
A o lo gari tira ti e n wo picture re yi papo kunna daada, a o ku si oju tira inu photo yen, a o we ni ikobere ni ona meji;
1/2
A o fi ikan sinu ikarahun igbin to tobi, a lo rii sinu abata; a o la eko elewe ni pansa, a o kii tira keji bo, a o pon eko yen pada, a o lo ri sinu abata.
Leyin ojo keje ki a maa reti esi lori eto yi.
CONFIRM LOCKING TO LEGIT 100% NI !!!
OSO AGBARA FIDIPOTE
E ba mi wa agbebo pepeiye kan, ki e du sinu agbada ijogun, a o la pepeiye naa laya pelu blade tuntun kan, a o fi eiyele funfun ooye kan si ninu, pelu eiye ega ako olori dudu meta, ati eso laa pupa lopolopo, eru alamo, odidi atare meta ati kerewu to po.
1/2
ASIRI IJINLE TI A FI N WO ENI TO YA WERE TABI WERE TO TI N BUGI JE SAN.
EROJA RE
Ewe odan to jabo sile funra re (mesan fun okunrin, meje fun obinrin
Ako alangba ooye kan (abo fun obinrin)
Ewe oparun tutu to po die
Okan elede tutu ti ko wo omi oojo
1/3
Okan aja tutu ti ko wo omi oojo
Odidi atare aja nla kan.
Afatan irun ori eni yen
SISE RE
A o mu were naa a o de mo le, a o fa gbogbo irun ori re ni afatan, a o da papo mo awon eroja to wa loke yi, a o jo gbogbo re papo, a o lo kunna daada.
2/3
ONA ABAYO BI AYE BA DE EEYAN MOLE TI KO SI ATUNSE KANKAN
Odidi ooye okete kan, a o gun ninu odo pelu ata ijosi die, eepo obo die, igi nla die, ewe orijin die pelu ose dudu
A o maa we ninu ajadi apeere laiwo bata fun ojo meje pelu omi to lo woorowo.
O daju !
OSE OSO OWO TO JINA GIDI 1000%โ
Ori oka kan
Ori odidere kan
Ori agbe kan
Ori aluko kan
Ewe ajeobale tutu
Ewe orijin tutu
Oga ooye kan
Ileke itun
Ileke ifa
Abeere
Aso funfun opa kan
A o gun gbogbo re papo mose dudu, a o wa kan apoti kekere kan.
1/2
a o fi aso funfun yi tele inu apoti yi, a o wa gbe oga ooye sori aso naa ninu apoti, a o wa ko ose yi le oga yi mole sinu apoti yi, a o wa se aso funfun yen bo mole, a o wa de apoti naa pa fun ojo merindinlogun (16 days).
2/3